Søg

Yoruba Comic on San Diego

Kopier dette storyboard
Yoruba Comic on San Diego

Storyboard Tekst

  • Glide: 1
  • Mo wo daadaa iwo nko Ekina
  • Bawo ni Ada
  • Mo wa daadaa
  • Glide: 2
  • Mo gbo pe o jade. Nibo ni o lo?
  • Mo lo si San Diego California.
  • Se o da lo ni?
  • Glide: 3
  • Mo gbadun eh pupo nitori California tuntun fun mi, ati weather daa gon.
  • Mo lo si irin ajo
  • E mi na fe lo si Cali, sugbon o won ju
  • Glide: 4
  • Oshe!! Beeni, mo lo si Sea World mo gbadun pupo nitori mo ri orcas ati dolphins. Mo fi owo mi sinu omi ati eja joko lori owo mi.
  • O fine gan!!! E mi na. Se o lo si ibomi ran?
  • Glide: 5
  • Ose gan mo dupe fun experience
  • Mo lo si irin ajo
  • Inu mi dun pe eh gbadun California
  • Se e le so fun mi nipa nkan to se nibe
  • Glide: 6
  • O da, mo gbadun San Diego California nitori mo lo si hotel ati luwee ni pool ni osan. Mo feran lati joko labe orun ati luwee ni pool. O n dun.
  • Se mo le ri aworan eh lati San Diego?
  • Glide: 7
  • Beeni mo dupe! Ose fun gbigbo!Odabo!
  • Mo ye ki n lo, mo fe to!Odabo!
  • Glide: 8
  • Beeni, gba. Mo lo si ile eranko pelu.
  • Kini oruko re?
  • Won n pe e ni San Diego Zoo. A ri eranko pupo nibe, sugbon koalas ati pandas ni mo feran ju ni tori awon mejeeji je ewe kan.
  • Glide: 9
  • Created by : Ekina
  • Glide: 10
  • Ayo mi po ni tori eja pupo wa lori owo mi
  • Ewooo! Mo nireti pe o gbadun California gan!
Over 40 millioner storyboards skabt
Ingen Downloads, Intet Kreditkort og Intet Login Nødvendigt for at Prøve!
Storyboard That Familie