Mājas Lapa
Resursi
Cenas
Izveidot Montāžas Skala
Izveidojiet Storyboard
Ielogoties
Reģistrēties kā skolotājam
Reģistrēties kā fiziska persona
Meklēt
Yoruba Comic on San Diego
Izveidojiet Storyboard
Kopējiet šo stāstu tabulu
ATSKAŅOT SLAIDRĀDI
IZLASI MAN
Izveidojiet savu
Kopēt
Montāžas Teksta
Slidkalniņš: 1
Mo wo daadaa iwo nko Ekina
Bawo ni Ada
Mo wa daadaa
Slidkalniņš: 2
Mo gbo pe o jade. Nibo ni o lo?
Mo lo si San Diego California.
Se o da lo ni?
Slidkalniņš: 3
Mo gbadun eh pupo nitori California tuntun fun mi, ati weather daa gon.
Mo lo si irin ajo
E mi na fe lo si Cali, sugbon o won ju
Slidkalniņš: 4
Oshe!! Beeni, mo lo si Sea World mo gbadun pupo nitori mo ri orcas ati dolphins. Mo fi owo mi sinu omi ati eja joko lori owo mi.
O fine gan!!! E mi na. Se o lo si ibomi ran?
Slidkalniņš: 5
Ose gan mo dupe fun experience
Mo lo si irin ajo
Inu mi dun pe eh gbadun California
Se e le so fun mi nipa nkan to se nibe
Slidkalniņš: 6
O da, mo gbadun San Diego California nitori mo lo si hotel ati luwee ni pool ni osan. Mo feran lati joko labe orun ati luwee ni pool. O n dun.
Se mo le ri aworan eh lati San Diego?
Slidkalniņš: 7
Beeni mo dupe! Ose fun gbigbo!Odabo!
Mo ye ki n lo, mo fe to!Odabo!
Slidkalniņš: 8
Beeni, gba. Mo lo si ile eranko pelu.
Kini oruko re?
Won n pe e ni San Diego Zoo. A ri eranko pupo nibe, sugbon koalas ati pandas ni mo feran ju ni tori awon mejeeji je ewe kan.
Slidkalniņš: 9
Created by : Ekina
Slidkalniņš: 10
Ayo mi po ni tori eja pupo wa lori owo mi
Ewooo! Mo nireti pe o gbadun California gan!